Isikiẹli 17:20 BM

20 N óo da àwọ̀n mi bò ó mọ́lẹ̀, pańpẹ́ mi yóo mú un, n óo sì mú un lọ sí Babiloni. Níbẹ̀ ni n óo ti ṣe ìdájọ́ rẹ̀ nítorí ìwà ọ̀tẹ̀ tí ó hù sí mi.

Ka pipe ipin Isikiẹli 17

Wo Isikiẹli 17:20 ni o tọ