Isikiẹli 18:14 BM

14 “Ṣugbọn bí eniyan burúkú yìí bá bí ọmọ, tí ọmọ yìí rí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí baba rẹ̀ ń dá, tí ẹ̀rù bà á, tí kò sì ṣe bíi baba rẹ̀,

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:14 ni o tọ