Isikiẹli 18:2 BM

2 “Kí ni ẹ rí tí ẹ fi ń pa irú òwe yìí nípa ilẹ̀ Israẹli, tí ẹ̀ ń sọ pé,‘Àwọn baba ni wọ́n jẹ èso àjàrà tí ó kan,ni eyín fi kan àwọn ọmọ?’

Ka pipe ipin Isikiẹli 18

Wo Isikiẹli 18:2 ni o tọ