Isikiẹli 20:16 BM

16 Nítorí pé wọ́n kọ ìlànà mi sílẹ̀, wọn kò tẹ̀lé òfin mi, wọ́n sì ba ọjọ́ ìsinmi mi jẹ́, nítorí pé ọkàn wọn kò kúrò lọ́dọ̀ àwọn oriṣa wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 20

Wo Isikiẹli 20:16 ni o tọ