Isikiẹli 20:20 BM

20 Ẹ máa pa àwọn ọjọ́ ìsinmi mi mọ́, kí wọ́n lè jẹ́ àmì láàrin èmi pẹlu yín, kí ẹ lè mọ̀ pé èmi OLUWA ni Ọlọrun yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 20

Wo Isikiẹli 20:20 ni o tọ