Isikiẹli 20:30 BM

30 Nítorí náà, sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé èmi OLUWA Ọlọrun ní ṣé ẹ óo máa ba ara yín jẹ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn baba yín, ẹ óo sì máa ṣìnà tẹ̀lé àwọn nǹkan ìríra wọn?

Ka pipe ipin Isikiẹli 20

Wo Isikiẹli 20:30 ni o tọ