Isikiẹli 20:34 BM

34 N óo ko yín jáde láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, n óo ko yín jọ láti gbogbo ilẹ̀ tí mo ti fi tipátipá fọ́n yín ká sí, pẹlu ọwọ́ líle, ati ibinu.

Ka pipe ipin Isikiẹli 20

Wo Isikiẹli 20:34 ni o tọ