Isikiẹli 22:18 BM

18 “Ìwọ ọmọ eniyan; àwọn ọmọ Israẹli ti di ìdàrọ́ lójú mi. Wọ́n dàbí idẹ, páànù, irin, ati òjé tí ó wà ninu iná alágbẹ̀dẹ. Wọ́n dàbí ìdàrọ́ ara fadaka.

Ka pipe ipin Isikiẹli 22

Wo Isikiẹli 22:18 ni o tọ