Isikiẹli 22:24 BM

24 “Ìwọ ọmọ eniyan, sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé ilẹ̀ tí kò mọ́ ni ilẹ̀ wọn, ilẹ̀ tí òjò kò rọ̀ sí lákòókò ibinu èmi OLUWA.

Ka pipe ipin Isikiẹli 22

Wo Isikiẹli 22:24 ni o tọ