Isikiẹli 22:30 BM

30 Mo wá ẹnìkan láàrin wọn tí ìbá tún odi náà mọ, kí ó sì dúró níbi tí odi ti ya níwájú mi láti bẹ̀bẹ̀ fún ilẹ̀ náà, kí n má baà pa á run, ṣugbọn n kò rí ẹnìkan.

Ka pipe ipin Isikiẹli 22

Wo Isikiẹli 22:30 ni o tọ