Isikiẹli 22:9 BM

9 Àwọn eniyan inú rẹ ń parọ́ láti paniyan. Wọ́n ń jẹbọ kiri lórí àwọn òkè ńláńlá, wọ́n sì ń ṣe ohun ìtìjú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 22

Wo Isikiẹli 22:9 ni o tọ