Isikiẹli 23:15 BM

15 tí wọ́n di àmùrè, tí wọ́n wé lawani gbọ̀ọ̀rọ̀ gbọ̀ọ̀rọ̀, tí gbogbo wọn dàbí ọ̀gá àwọn oníkẹ̀kẹ́ ogun, àwọn ọmọ ogun ará Babilonia.

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:15 ni o tọ