Isikiẹli 23:6 BM

6 àwọn ọmọ ogun tí wọn ń wọ aṣọ àlàárì, àwọn gomina ati àwọn ọ̀gágun, ati àwọn ẹlẹ́ṣin, ọdọmọkunrin ni gbogbo wọn, ojú wọn sì fanimọ́ra.

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:6 ni o tọ