Isikiẹli 24:7 BM

7 Nítorí pé ẹ̀jẹ̀ eniyan tí ó pa wà ninu rẹ̀, orí àpáta ni ó da ẹ̀jẹ̀ wọn sí, kò dà á sórí ilẹ̀, tí yóo fi rí erùpẹ̀ bò ó.

Ka pipe ipin Isikiẹli 24

Wo Isikiẹli 24:7 ni o tọ