Isikiẹli 25:16 BM

16 nítorí náà, n óo nawọ́ ìyà sí wọn, n óo pa àwọn ọmọ Kereti run, n óo pa àwọn tí ó kù sí etí òkun rẹ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 25

Wo Isikiẹli 25:16 ni o tọ