Isikiẹli 26:18 BM

18 Àwọn erékùṣù yóo wárìrì ní ọjọ́ ìṣubú rẹ.Nítòótọ́, àwọn erékùṣù tí wọ́n wà ninu òkun yóo dààmú nítorí ìparun rẹ.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 26

Wo Isikiẹli 26:18 ni o tọ