Isikiẹli 27:10 BM

10 “Àwọn ará Pasia ati àwọn ará Ludi ati àwọn ará Puti wà láàrin àwọn ọmọ ogun rẹ bí akọni. Wọ́n gbé asà ati àṣíborí wọn kọ́ sinu rẹ, wọ́n jẹ́ kí o gba ògo.

Ka pipe ipin Isikiẹli 27

Wo Isikiẹli 27:10 ni o tọ