Isikiẹli 27:17 BM

17 Juda ati ilé Israẹli bá ọ ṣòwò: wọ́n ń kó ọkà, èso olifi, àkọ́so èso ọ̀pọ̀tọ́, oyin, òróró ati òrí wá láti fi ṣe pàṣípààrọ̀ àwọn nǹkan tí ò ń tà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 27

Wo Isikiẹli 27:17 ni o tọ