Isikiẹli 27:19 BM

19 Àwọn ará Fedani ati Jafani láti Usali a máa wá fi ọtí waini pààrọ̀ ohun tí ò ń tà; wọn a kó àwọn nǹkan èlò irin wá, ati igi kasia.

Ka pipe ipin Isikiẹli 27

Wo Isikiẹli 27:19 ni o tọ