Isikiẹli 27:33 BM

33 Nígbà tí àwọn ọjà rẹ bá dé láti òkè òkun,ò ń tẹ́ ọpọlọpọ eniyan lọ́rùn.Ò ń fi ọpọlọpọ ọrọ̀ rẹ ati ọjà rẹsọ àwọn ọba ayé di ọlọ́rọ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 27

Wo Isikiẹli 27:33 ni o tọ