Isikiẹli 27:35 BM

35 “Ẹnu ya gbogbo àwọn tí ń gbé etí òkun nítorí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí ọ. Àwọn ọba wọn ń gbọ̀n jìnnìjìnnì, ẹ̀rù sì hàn ní ojú wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 27

Wo Isikiẹli 27:35 ni o tọ