Isikiẹli 27:5 BM

5 Igi firi láti Seniri ni wọ́n fi ṣe gbogbo ẹ̀gbẹ́ rẹ.Igi kedari láti Lẹbanoni ni wọ́n sì fi ṣe òpó ọkọ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 27

Wo Isikiẹli 27:5 ni o tọ