Isikiẹli 28:19 BM

19 Gbogbo àwọn tí wọ́n mọ̀ ọ́ láàrin àwọn eniyan láyé ni ó yà lẹ́nu nígbà tí wọ́n rí ọ. Òpin burúkú ti dé bá ọ, o kò sì ní sí mọ́ títí ayé.’ ”

Ka pipe ipin Isikiẹli 28

Wo Isikiẹli 28:19 ni o tọ