Isikiẹli 3:7 BM

7 Ṣugbọn àwọn ọmọ Israẹli kò ní gbọ́ tìrẹ, nítorí pé wọn kò fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi. Olóríkunkun ati ọlọ́kàn líle ni gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 3

Wo Isikiẹli 3:7 ni o tọ