Isikiẹli 30:5 BM

5 “ ‘Àwọn ará Etiopia, ati Puti, ati Ludi, ati gbogbo ilẹ̀ Arabia ati Libia, ati gbogbo àwọn eniyan wa tí wọ́n jọ gbìmọ̀ pọ̀, ni ogun yóo pa.’ ”

Ka pipe ipin Isikiẹli 30

Wo Isikiẹli 30:5 ni o tọ