Isikiẹli 30:8 BM

8 Wọn yóo mọ̀ pé èmi ni OLUWA nígbà tí mo bá dáná sun Ijipti, tí gbogbo àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ bá ṣubú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 30

Wo Isikiẹli 30:8 ni o tọ