Isikiẹli 31:5 BM

5 Nítorí náà, ó ga sókè fíofío, ju gbogbo igi inú igbó lọ.Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ tóbi, wọ́n sì gùn,nítorí ọpọlọpọ omi tí ó ń rí.

Ka pipe ipin Isikiẹli 31

Wo Isikiẹli 31:5 ni o tọ