Isikiẹli 32:22 BM

22 “Asiria náà wà níbẹ̀, pẹlu gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀. Ibojì àwọn tí wọ́n ti kú yí i ká. Gbogbo wọn ni wọ́n ti kú ikú ogun.

Ka pipe ipin Isikiẹli 32

Wo Isikiẹli 32:22 ni o tọ