Isikiẹli 33:4 BM

4 bí ẹnìkan bá gbọ́ ìró fèrè náà, ṣugbọn tí kò bá bìkítà fún ogun àgbọ́-tẹ́lẹ̀ yìí, bí ogun bá pa á orí ara rẹ̀ ni ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yóo wà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 33

Wo Isikiẹli 33:4 ni o tọ