Isikiẹli 34:19 BM

19 Ṣé àjẹkù tí ẹ ti fi ẹsẹ̀ tẹ̀ mọ́lẹ̀ ni ó yẹ kí àwọn aguntan tèmi máa jẹ; omi àmukù tí ẹ ti fi ẹsẹ̀ dàrú sì ni ó yẹ kí wọn máa mu?

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:19 ni o tọ