Isikiẹli 34:26 BM

26 “N óo bukun àwọn, ati gbogbo agbègbè òkè mi. N óo máa jẹ́ kí òjò máa rọ̀ lásìkò wọn, òjò ibukun ni yóo sì máa jẹ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:26 ni o tọ