Isikiẹli 34:29 BM

29 N óo fún wọn ní ọpọlọpọ nǹkan kórè ninu ohun tí wọ́n bá gbìn, ìyàn kò ní run wọ́n mọ́ ní ilẹ̀ náà, àwọn orílẹ̀-èdè yòókù kò sì ní fi wọ́n ṣẹ̀sín mọ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 34

Wo Isikiẹli 34:29 ni o tọ