Isikiẹli 35:10 BM

10 “ ‘Nítorí ẹ̀yin ará Edomu sọ pé, àwọn orílẹ̀-èdè mejeeji wọnyi ati ilẹ̀ wọn yóo di tiyín ati pé ẹ óo jogún rẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé OLUWA wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 35

Wo Isikiẹli 35:10 ni o tọ