Isikiẹli 35:12 BM

12 Ẹ óo mọ̀ pé èmi OLUWA gbọ́ gbogbo ohun tí ẹ̀ ń sọ sí àwọn òkè Israẹli, pé wọ́n ti di ahoro ati ìkógun fun yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 35

Wo Isikiẹli 35:12 ni o tọ