Isikiẹli 35:5 BM

5 “ ‘Nítorí pé ò ń fẹ́ràn ati máa ṣe ọ̀tá lọ títí, o sì fa àwọn ọmọ Israẹli fún ogun pa nígbà tí ìṣòro dé bá wọn, tí wọn ń jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 35

Wo Isikiẹli 35:5 ni o tọ