Isikiẹli 36:19 BM

19 Mo fọ́n wọn ká sáàrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, wọ́n sì tú káàkiri orí ilẹ̀ ayé. Ìwà ati ìṣe wọn ni mo fi dá wọn lẹ́jọ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 36

Wo Isikiẹli 36:19 ni o tọ