Isikiẹli 36:21 BM

21 Ṣugbọn mo ní ìtara fún orúkọ mímọ́ mi, tí àwọn ọmọ Israẹli sọ di nǹkan yẹ̀yẹ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 36

Wo Isikiẹli 36:21 ni o tọ