Isikiẹli 36:31 BM

31 Nígbà náà ni ẹ óo ranti ìrìnkurìn ati ìwà burúkú yín, ara yín óo sì su yín nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín ati ìwà ìríra yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 36

Wo Isikiẹli 36:31 ni o tọ