Isikiẹli 36:8 BM

8 Ṣugbọn ẹ̀yin òkè Israẹli, igi óo hù lórí yín, wọn óo sì so èso fún Israẹli, àwọn eniyan mi, nítorí pé wọn kò ní pẹ́ pada wálé.

Ka pipe ipin Isikiẹli 36

Wo Isikiẹli 36:8 ni o tọ