Isikiẹli 37:14 BM

14 N óo fi ẹ̀mí mi sinu yín, ẹ óo sì tún wà láàyè; n óo sì mu yín wá sí ilẹ̀ yín. Ẹ óo wá mọ̀ pé èmi OLUWA ni mo wí bẹ́ẹ̀, tí mo sì ṣe bẹ́ẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:14 ni o tọ