Isikiẹli 37:21 BM

21 kí o sọ fún wọn pé OLUWA Ọlọrun ní, ‘Ẹ wò ó! N óo kó àwọn ọmọ Israẹli jọ láti gbogbo orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà, n óo kó wọn jọ láti ibi gbogbo wá sí ilẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:21 ni o tọ