Isikiẹli 37:28 BM

28 Àwọn orílẹ̀-èdè yòókù yóo wá mọ̀ pé èmi OLUWA ni mo ya Israẹli sọ́tọ̀, nígbà tí ibi mímọ́ mi bá wà láàrin wọn títí lae.’ ”

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:28 ni o tọ