Isikiẹli 37:8 BM

8 Kí n tó ṣẹ́jú pẹ́, iṣan ti dé ara wọn, ẹran ti bo iṣan, awọ ara sì ti bò wọ́n, ṣugbọn kò tíì sí èémí ninu wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:8 ni o tọ