Isikiẹli 38:21 BM

21 N óo dá oríṣìíríṣìí ẹ̀rù ba Gogu, lórí òkè mi, àwọn ọmọ ogun rẹ̀ yóo fa idà yọ sí ara wọn. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 38

Wo Isikiẹli 38:21 ni o tọ