Isikiẹli 38:23 BM

23 N óo fi títóbi mi ati ìwà mímọ́ mi hàn lójú àwọn orílẹ̀-èdè, wọn yóo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 38

Wo Isikiẹli 38:23 ni o tọ