Isikiẹli 38:9 BM

9 Ẹ óo gbéra, ẹ óo máa bọ̀ bí ìjì líle, ẹ óo dàbí ìkùukùu tí ó bo ilẹ̀, ìwọ ati gbogbo ọmọ ogun rẹ, pẹlu ọpọlọpọ eniyan tí ó wà pẹlu rẹ.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 38

Wo Isikiẹli 38:9 ni o tọ