Isikiẹli 39:20 BM

20 Ẹ óo jẹ ẹṣin ati àwọn tí wọn ń gùn wọ́n, àwọn alágbára ati oríṣìíríṣìí àwọn ọmọ ogun níbi àsè tí n óo sè fun yín.’ Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 39

Wo Isikiẹli 39:20 ni o tọ