Isikiẹli 4:13 BM

13 OLUWA ní: “Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ Israẹli yóo ṣe máa jẹ oúnjẹ wọn ní àìmọ́, láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tí òun óo lé wọn sí.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 4

Wo Isikiẹli 4:13 ni o tọ