Isikiẹli 40:24 BM

24 Ó mú mi lọ sí apá ìhà gúsù, mo sì rí ẹnu ọ̀nà kan níbẹ̀. Ó wọn àtẹ́rígbà ati ìloro rẹ̀, wọ́n sì rí bákan náà pẹlu àwọn yòókù.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:24 ni o tọ