Isikiẹli 40:27 BM

27 Ẹnu ọ̀nà kan wà ní ìhà gúsù gbọ̀ngàn inú. Ó wọn ibẹ̀, láti ẹnu ọ̀nà náà sí ẹnu ọ̀nà tí ó wà ní ìhà gúsù, jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45).

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:27 ni o tọ